Jóòbù 19:11-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ó sì tinábọ ìbínú rẹ̀ sími,ó sì kà mí sí bí ọ̀kan nínú àwọn ọ̀tá rẹ̀.

12. Ẹgbẹ́ ogun rẹ̀ sì dàpọ̀ sí mi, wọ́nsì mọ odi yí mi ká, wọ́n sì yíàgọ́ mi ká.

13. “Ó mú àwọn arákùnrin mi jìn nàsí mi réré, àti àwọn ojúlùmọ̀ midi àjèjì sí mi pátapáta.

14. Àwọn alájọbí mi fà sẹ́yìn, àwọnafaramọ́ ọ̀rẹ́ mi sì di onígbàgbé mi.

15. Àwọn ará inú ilé mi àti àwọnìránṣẹ́bìnrin mi kà mí sí àjèjì;èmi jásí àjèjì ènìyàn ní ojú wọn.

16. Mo pe ìránṣẹ́ mi, òun kò sì dá milóhùn; mo fi ẹnu mi bẹ̀ ẹ́.

Jóòbù 19