Jóòbù 16:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbáṣe pé ẹnìkan le è máa ṣe alágbàwífún ẹnìkejì lọ́dọ̀ Ọlọ́run,bí ènìyàn kan ti íṣe alágbàwí fún ẹnìkejì rẹ̀.

Jóòbù 16

Jóòbù 16:13-22