Jóòbù 15:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ayọ̀ àwọn àgàbàgebèyóò túká, iná ní yóò sì jó àgọ́ àwọn tí ó fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Jóòbù 15

Jóòbù 15:26-35