Jóòbù 14:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ènìyàn tí a bí nínú obìnrinọlọ́jọ́ díẹ̀ ni, ó sì kún fún ìpọ́njú.

2. Ó jáde wá bí ìtànná ewéko, a sìké e lulẹ̀; Ó sì ń fò lọ bí òjìji, kò sì dúró pẹ́.

3. Ìwọ sì ń síjú rẹ wò irú èyí ni?Ìwọ sì mú mi wá sínú ìdájọ́ pẹ̀lú rẹ?

Jóòbù 14