Jóòbù 13:27-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Ìwọ kàn àbà mọ́ mi lẹ́ṣẹ̀ pẹ̀lú,ìwọ sì ń wò ipa ọ̀nà ìrìn mi ní àwòfín;Ìwọ sì ń fi ìlà yí gìgisẹ̀ mi ká.

28. “Àní, yí ẹni tí á ti run ká, bí ohuntí ó bu, Bí aṣọ tí kòkòrò jẹ bàjẹ́.

Jóòbù 13