Jóòbù 10:7-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Ìwọ mọ̀ pé èmi kì í ṣe oníwà búburú,kò sì sí ẹni tí ó le gbà mí kúrò ní ọwọ́ rẹ?

8. “Ọwọ́ rẹ ni ó dámi,tí ó sì mọ mí pọ̀ yíkákiri;síbẹ̀ ìwọ sì ńbà mí jẹ́.

9. Èmi bẹ̀ ọ́ rántí pé ìwọ tí ìwọ timọ mí bí amọ̀; ìwọ yóò ha sìtún mú mi lọ padà sí erùpẹ̀?

Jóòbù 10