Jóòbù 10:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Ìwọ ti fún mi ní ẹ̀mí àti ojú rere,ìbẹ̀wò rẹ sì pa ọkàn mi mọ́.

13. “Nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ sì ti fi pamọ́ nínú rẹ;èmi mọ̀ pé, èyí ń bẹ ní ọkàn rẹ.

14. Bí mo bá ṣẹ̀, nígbà náà ni ìwọ yóò máa ṣọ́miìwọ kì yóò sì dárí àìṣedédé mi jìn.

Jóòbù 10