Nítorí tí ìwọ ti sọ mí sínú ibú,ní àárin òkun,ìṣàn omi sì yí mi káàkiri;gbogbo bíbì omi àti rírú omiré kọjá lórí mi.