Jòhánù 7:52-53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

52. Wọ́n dáhùn wọ́n sì wí fún un pé, “Ìwọ pẹ̀lú wá láti Gálílì bí? Wá kiri, kí o sì wò nítorí kò sí wòlíì kan tí ó ti Gálílì dìde.”

53. Wọ́n sì lọ olúkúlùkù sí ilé rẹ̀.

Jòhánù 7