Jòhánù 5:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, àjọ àwọn Júù kan kò; Jésù sì gòkè lọ sí Jérúsálẹ́mù.

2. Adágún omi kan sì wà ní Jérúsálẹ́mù, létí bodè àgùntàn, tí a ń pè ní Bẹtiṣáídà ní èdè Hébérù, tí ó ní ìloro márùn-ún.

Jòhánù 5