Jòhánù 2:24-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ṣùgbọ́n Jésù kò gbé ara lé wọn, nítorí tí ó mọ gbogbo ènìyàn.

25. Òun kò sì nílò ẹ̀rí nípa ènìyàn: nítorí tí Ó mọ̀ ohun tí ń bẹ nínú ènìyàn.

Jòhánù 2