Jòhánù 16:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nǹkan wọ̀nyí ni mo ti sọ fún yín tẹ́lẹ̀, kí ẹ̀yin kí ó lè ní àlàáfíà nínú mi. Nínú ayé, ẹ̀yin ó ní ìpọ́njú; ṣùgbọ́n ẹ tújúká; mo ti ṣẹ́gun ayé.”

Jòhánù 16

Jòhánù 16:26-33