Jòhánù 10:41-42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Àwọn ènìyàn púpọ̀ sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Jòhánù kò ṣe iṣẹ́ àmì kan: Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni ohun gbogbo tí Jòhánù sọ nípa ti ọkùnrin yìí.”

42. Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbàágbọ́.

Jòhánù 10