Jóẹ́lì 1:19-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Olúwa, sí ọ ni èmi o ké pè,nítorí iná tí run pápa oko tútú ihà,ọwọ́ iná sí ti jó gbogbo igi igbó.

20. Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú:nítorí tí àwọn iṣàn omi gbẹ,iná sí ti jó àwọn pápá oko ihà run.

Jóẹ́lì 1