Jeremáyà 49:37-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Èmi yóò kẹ́gàn Élámù lójúàwọn ọ̀tá rẹ̀ àti lọ́dọ̀ àwọntí wọ́n jọ ń gbé.Èmi yóò mú ibi wá sí orí wọn,pàápàá ìbínú gbígbóná mi;”bẹ́ẹ̀ ni Olúwa wí.“Èmi yóò lé wọn pẹ̀lú idà, di ìgbà tí èmi yóò rẹ́yìn wọn.

38. Èmi yóò sì pa Ọba wọn run àti olórí wọn,”báyìí ni Olúwa wí.

39. “Ṣíbẹ̀, èmi yóò dá ìkólọẸ́lámù padà láìpẹ́ ọjọ́,”báyìí ni Olúwa wí.

Jeremáyà 49