Jeremáyà 48:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ jẹ́ kí a mú u mutínítorí ó kó ìdọ̀tí bá Olúwa,jẹ́ kí Móábù pàfọ̀ nínú èébì rẹ̀,kí ó di ẹni ẹ̀gàn.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:22-29