22. Nítorí náà, ẹ̀yin yóò jẹ́ ènìyàn mi,èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín,’ ”ni Olúwa wí.
23. Wò ó, ìbínú Ọlọ́run yóò tú jáde,ìjì líle yóò sì sọ̀kalẹ̀ sórí àwọn ènìyàn búburú.
24. Ìbínú ńlá Ọlọ́run kò ní dẹ̀yìn lẹ́yìnàwọn ìkà títí yóò fi múèròǹgbà ọkàn rẹ̀ ṣẹ.Ní àìpẹ́ ọjọ́,òye rẹ̀ yóò yé e yín.