Jẹ́nẹ́sísì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ìṣun ibú àti fèrèsé ìṣàn ọ̀run tì, òjò pẹ̀lú sì dáwọ́ rírọ̀ dúró.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:1-5