Jẹ́nẹ́sísì 6:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú onírúurú oúnjẹ wá sínú ọkọ̀ kí o pa wọ́n mọ́ fún jíjẹ gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wà nínú ọkọ̀ àti ènìyàn àti ẹranko.”

Jẹ́nẹ́sísì 6

Jẹ́nẹ́sísì 6:11-22