Jẹ́nẹ́sísì 50:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàtọ̀ fún gbogbo àwọn ará ilé Jóṣẹ́fù àti ti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn tí ó jẹ́ ilé baba rẹ̀, àwọn ọmọ wọn nìkan àti agbo ẹran pẹ̀lú agbo màlúù ni ó sẹ́ kù ní Gósénì.

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:3-17