Jẹ́nẹ́sísì 50:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò wí pé, “Gòkè lọ, kí o sì sin baba rẹ, bí ó tí mú ọ búra.”

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:3-8