Jẹ́nẹ́sísì 50:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ogójì ọjọ́ ni wọ́n fi ṣe èyí, nítorí èyí ni àsìkò tí a máa ń fi ṣe ẹ̀ǹbáàmù òkú. Àwọn ará Éjíbítì sì sọ̀fọ̀ rẹ̀ fún àádọ́rin ọjọ́.

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:1-7