Jẹ́nẹ́sísì 50:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn arákùnrin rẹ̀ wá, wọ́n sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n wí pé, “Ẹrú rẹ ni a jẹ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:8-26