Jẹ́nẹ́sísì 5:31-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Àpapọ̀ ọdún rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rin-ọdún-ó-dín-mẹ́talélógún (777), ó sì kú.

32. Lẹ́yìn tí Nóà pé ọmọ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún (500) ni ó bí Ṣémù, Ámù àti Jáfétì.

Jẹ́nẹ́sísì 5