Jẹ́nẹ́sísì 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí ó wà láàyè fún ẹgbẹ̀rin-dín-méjìdínlógún ọdún (782), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:17-32