Jẹ́nẹ́sísì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí, ó wà láàyè fún ẹgbẹ̀rin ọdún (800) ó sì bí àwọn ọmọkúnrin àti ọmọbìnrin.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:11-27