Jẹ́nẹ́sísì 49:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni ríru bí omi òkun, ìwọ kì yóò tayọ mọ́,nítorí pé ìwọ gun ibùsùn baba rẹ,lórí àkéte mi, ìwọ sì bà á jẹ́(ìwọ bá ọ̀kan nínú àwọn aya baba rẹ lò pọ̀).

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:1-6