Jẹ́nẹ́sísì 49:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìbùkún baba rẹ pọ̀ púpọ̀ju ìbùkún àwọn òkè ńlá ìgbàanì,ju ẹ̀bùn ńlá àwọn òkè láéláé.Jẹ́ kí gbogbo èyí sọ̀kalẹ̀ sí orí Jóṣẹ́fù,lé ìpéǹpéjú ọmọ aládé láàrin arákùnrin rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:25-29