Jẹ́nẹ́sísì 49:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, kí ẹ sì tẹ́tí, ẹ̀yin ọmọ Jákọ́bù;Ẹ fetí sí Ísírẹ́lì baba yín.

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:1-10