Jẹ́nẹ́sísì 49:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣébúlúnì yóò máa gbé ní etí òkun,yóò sì jẹ́ èbúté fún ọkọ̀ ojú omi,agbégbé rẹ yóò tàn ká títí dé Ṣídónì.

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:11-18