Jẹ́nẹ́sísì 48:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù wí fun pé, “Rárá, baba mi, èyí ni àkọ́bí, orí rẹ̀ ni kí ìwọ kí o gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ lé.”

Jẹ́nẹ́sísì 48

Jẹ́nẹ́sísì 48:9-22