Jẹ́nẹ́sísì 48:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí, ojú Ísírẹ́lì ti ń di bàìbàì nítorí ogbó, agbára káká sì ni ó fi ń ríran. Jósẹ́fù sì kó àwọn ọmọ rẹ̀ súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀, baba rẹ̀ fẹnu kò wọ́n ni ẹnu, ó sì dì mọ́ wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 48

Jẹ́nẹ́sísì 48:6-16