Jẹ́nẹ́sísì 47:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù wí pé, “Búra fún mi,” Jósẹ́fù sì búra fún un. Ísírẹ́lì sì tẹ orí rẹ̀ ba, bí ó ti sinmi lé ori ìbùsùn rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 47

Jẹ́nẹ́sísì 47:27-31