Jẹ́nẹ́sísì 47:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n dá á lóhùn pé, “O ti gbà wá là, Ǹjẹ́ kí a rí ojúrere níwájú olúwa wa, àwa yóò di ẹrú Fáráò.”

Jẹ́nẹ́sísì 47

Jẹ́nẹ́sísì 47:20-27