Jẹ́nẹ́sísì 45:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyàn tí ó ti mú láti ọdún méjì sẹ́yìn yìí yóò tẹ̀ ṣíwájú fún ọdún márùn ún sí i nínú èyí tí ẹnikẹ́ni kò ní gbìn, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ni kórè.

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:4-12