Jẹ́nẹ́sísì 45:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni wọ́n jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì wá sí ọ̀dọ̀ Jákọ́bù baba wọn ní ilẹ̀ Kénánì.

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:23-28