Jẹ́nẹ́sísì 45:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ sọ fún baba mi nípa gbogbo ọlá tí a fún mi ní ilẹ̀ Éjíbítì àti ohun gbogbo tí ẹ̀yin ti rí, kí ẹ sì mú baba mi tọ̀ mí wá sí ìhín yìí kíákíá.”

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:9-19