Jẹ́nẹ́sísì 42:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Arákùnrin méjìlá ni wá, ọmọ bàbá kan náà, ọ̀kan ti kú, èyí tí ó jẹ́ àbíkẹ́yìn wà lọ́dọ̀ baba wa ni ilẹ̀ Kénánì.’

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:23-37