Jẹ́nẹ́sísì 42:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n padà dé ọ̀dọ̀ Jákọ́bù baba wọn, wọ́n ròyìn gbogbo ohun tí ó sẹlẹ̀ fún-un wí pé,

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:25-30