Jẹ́nẹ́sísì 42:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi tí wọ́n ti dúró láti sùn lóru ọjọ́ náà, ọ̀kan nínú wọn tú àpò rẹ̀ láti mú oúnjẹ fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, ó sì rí owó rẹ̀ ní ẹnu àpò rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:24-35