Jẹ́nẹ́sísì 42:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúbẹ́nì fèsì pé, “Ǹjẹ́ ń ò wí fún yín pé kí ẹ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ ọmọdé-kùnrin náà? Ṣùgbọ́n ẹ kò gbọ́! Nisinsin yìí a ń béèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ wa.”

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:20-26