Jẹ́nẹ́sísì 42:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó bá jẹ́ pé olótìítọ́ ènìyàn ni yín, ẹ jẹ́ kí ọkan nínú yín dúró ni àtìmọ́lé ní ìhín, nígbà tí àwọn yókù u yín yóò gbé ọkà lọ fún àwọn ará ilé e yín tí ebi ń pa.

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:17-25