Jẹ́nẹ́sísì 40:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láàrin ọjọ́ mẹ́ta Fáráò yóò mú ọ jáde nínú ẹ̀wọ̀n padà sí ipò rẹ, ìwọ yóò sì tún máa gbọ́tí fún-un, gẹ́gẹ́ bí ìṣe rẹ àtẹ̀yìnwá.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:11-22