Jẹ́nẹ́sísì 38:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà sì dá wọn mọ̀, ó sì wí pé, “O ṣe olódodo jù mí lọ, níwọ̀n ìgbà tí n kò fi fún Ṣélà ọmọ mi.” Kò sì bá a lò pọ̀ mọ́ láti ọjọ́ náà.

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:21-30