Jẹ́nẹ́sísì 38:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà sì bi í pé, “Ẹ̀rí wo ni kí n fún ọ?”Ó sì dáhùn pé, “Èdìdì ìdámọ̀ okùn àti ọ̀pá ìtìlẹ̀ rẹ ti ń bẹ ní ọwọ́ rẹ.” Ó sì kó wọn fún un, ó sì sùn tì í, obìnrin náà sì lóyún nípaṣẹ̀ rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:12-21