Jẹ́nẹ́sísì 36:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jóbábù kú, Úṣámù láti ilẹ̀ Témánì sì jọba ní ipò rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:31-36