Jẹ́nẹ́sísì 36:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kórà, Gátamù àti Ámálékì. Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ Élífásì ní Édómù wá, wọ́n jẹ́ ọmọ-ọmọ Ádà.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:11-26