Jẹ́nẹ́sísì 35:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísírẹ́lì sì ń bá ìrìn-àjò rẹ̀ lọ, ó sì pa àgọ́ rẹ̀ sí Migida-Édérì (ilé-ìsọ́ Édérì).

Jẹ́nẹ́sísì 35

Jẹ́nẹ́sísì 35:16-27