Jẹ́nẹ́sísì 35:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Jákọ́bù wí fún gbogbo ará ilé rẹ̀ pé, “Ẹ mú gbogbo àjòjì òrìsà tí ó wà lọ́dọ̀ yín kúrò, kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì pààrọ̀ aṣọ yín.

Jẹ́nẹ́sísì 35

Jẹ́nẹ́sísì 35:1-4