Jẹ́nẹ́sísì 31:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì ránṣẹ́ pe Rákélì àti Líà sí pápá níbi tí àwọn ohun ọ̀sìn rẹ̀ wà.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:1-12